Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekáyà gba ìwé náà lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ ó sì kà á. Lẹ́yìn náà ni ó gòkè lọ sí tẹ́ḿpìlì Olúwa ó sì tẹ́ ìwé náà sílẹ̀ níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:14 ni o tọ