Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 36:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá sì sọ fún mi pé, “Àwa gbẹ́kẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run wa,” kì í ṣe òun ni Heṣekáyà ti mú àwọn ibi gíga àti pẹpẹ rẹ̀ kúrò, tí ó sì wí fún Júdà àti Jérúsálẹ́mù pé, “Ẹ̀yin gbọdọ̀ sìn níwájúu pẹpẹ yìí”?

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:7 ni o tọ