Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 36:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sọ wí pé ìwọ ní ète àti agbára ogun—ṣùgbọ́n ìwọ ń sọ ọ̀rọ̀ aṣán. Ta ni ìwọ gbẹ́kẹ̀lé tí ìwọ fi ṣọ̀tẹ̀ sí mi?

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:5 ni o tọ