Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 36:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, ǹjẹ́ mo wa lè wá bá ilẹ̀ yìí jà kí n sì pa á run láìsí Olúwa? Olúwa fún rara rẹ̀ ló sọ pé kí n bá orílẹ̀ èdè yìí jà kí n sì paárun.’ ”

Ka pipe ipin Àìsáyà 36

Wo Àìsáyà 36:10 ni o tọ