Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 34:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ogun ọ̀run ni yóò di yíyọ́,a ó sì ká àwọn ọ̀run jọ bí i takàdá,gbogbo ogun wọn yóò si ṣubú lulẹ̀,bí ewé ti n bọ́ kúrò lára àjàrà,àti bí i bíbọ́ èṣo lára igi ọ̀pọ̀tọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 34

Wo Àìsáyà 34:4 ni o tọ