Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù,ojú ti Lẹ́bánónì ó sì ṣáṢárónì sì dàbí aginjù,àti Báṣánì òun Kámẹ́lì rẹ àwọn èwe wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:9 ni o tọ