Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èrù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Ṣíhónì;ìwárìrì bá àwọn tí kò gba Ọlọ́run gbọ́:“Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú iná ajónirun?Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú ìjóná àìnípẹ̀kun?”

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:14 ni o tọ