Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ọ, ìwọ apanirun,ìwọ tí a kò tí ì pa ọ́ run!Ègbé ni fún ọ, ìwọ ọ̀dàlẹ̀,ìwọ tí a kò tí ì dà ọ́!Nígbà tí o bá dẹ́kun à ń panirun;a ó pa ìwọ náà run,nígbà tí o bá dẹ́kun à ń dani,a ó da ìwọ náà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:1 ni o tọ