Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:19-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹṣẹàti tí ojú ìlú ti tẹ́ pẹrẹṣẹ pátapáta,

20. báwo ni ẹ ó ti jẹ́ alábùkún tó,nípa gbíngbin irúgbìn sí ipa odò gbogbo,àti nípa jíjẹ́ kí àwọn màlúù yín àtiàwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ jẹ láìsí ìdíwọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32