Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:17-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Èṣo òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà;àbájáde òdodo yóò sì jẹ́ ìdákẹ́jẹ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé títí láé.

18. Àwọn ènìyàn mi yóò máa gbé ní àlàáfíà ní ibùgbé àlàáfíà,ní àwọn ilé ààbò,ní àwọn ibi ìsinmi tí kò ti sí ìdíwọ́.

19. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹṣẹàti tí ojú ìlú ti tẹ́ pẹrẹṣẹ pátapáta,

20. báwo ni ẹ ó ti jẹ́ alábùkún tó,nípa gbíngbin irúgbìn sí ipa odò gbogbo,àti nípa jíjẹ́ kí àwọn màlúù yín àtiàwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ jẹ láìsí ìdíwọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32