Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti fún ilẹ̀ àwọn ènìyàn miilẹ̀ tí ó ti kún fún ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n—bẹ́ẹ̀ ni, kẹ́dùn fún gbogbo ilé ìturaàti fún ìlú àríyá yìí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:13 ni o tọ