Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wárìrì, ẹ̀yin obìnrin onítẹ̀lọ́rùnbẹ̀rù, ẹ̀yin ọ̀dọ́mọbìnrin tí ẹ rò pé ọkàn yín balẹ̀!Ẹ bọ́ aṣọ yín kúrò,ẹ ró aṣọ ọ̀fọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ẹ yín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:11 ni o tọ