Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, èyí ni ohun tí Ẹni-Mímọ́ Ísírẹ́lì wí:“Nítorí pé ẹ ti kọ ọ̀rọ̀ yìí sílẹ̀,ẹ gbáralé ìnilárakí ẹ sì gbọ́kànlé ẹ̀tàn,

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:12 ni o tọ