Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwò ojú wọn ń jẹ́rìí lòdì sí wọn,wọ́n ń polongo ẹ̀ṣẹ̀ wọn bí i Sódómù;wọn ò fi pamọ́!Ègbé ni fún wọn!Wọ́n ti mú ìparun wá sórí ara wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 3

Wo Àìsáyà 3:9 ni o tọ