Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí pé,“Àwọn obìnrin Ṣíónì jẹ́ agbéraga,wọn ń rìn lọ pẹ̀lú ọrùn tí ó nà tàntàn,tí wọn ń fojú pe ọkùnrin,tí wọn ń sọ̀dí bí wọn ti ń yan lọpẹ̀lú ohun ọ̀ṣọ́ tí ń mì wọnjan wọnjan lọ́rùn ẹṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 3

Wo Àìsáyà 3:16 ni o tọ