Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọ̀dọ̀mọdé ni o ń pọ́n àwọn ènìyàn mi lójúàwọn obìnrin ń jọba lé wọn lórí.Áà! Ènìyàn mi àwọn afinimọ̀nà yín ti sìyín lọ́nà,wọn sì mú yín kúrò ní ipa ọ̀nà yín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 3

Wo Àìsáyà 3:12 ni o tọ