Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òdòdó tí ó ń rọ náà tí í ṣe ẹwà ògo rẹ̀,tí ó tò sí orí àfonífojì ẹlẹ́tù lójú,yóò dàbí èso ọ̀pọ̀tọ́ tí ó pọ́n ṣáájú ìkóórèbí ẹnikẹ́ni bá ti rí i tí ó sì mú un ní ọwọ́ọ rẹ̀,òun a sì mì ín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:4 ni o tọ