Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí ó bá ti tẹ́ ilẹ̀ pẹrẹṣẹòun kì yóò ha gbìn káráwè kíó sì fọ́n irúgbìn kúmínì ká bí?Òun kì yóò ha gbin jéró sí àyè e tirẹ̀ọkà báálì sì àyè e tirẹ̀,àti Ṣípẹ́lítì ní oko tirẹ̀?

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:25 ni o tọ