Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ìdí èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa sí wọn yóò di péṣe kí o ṣe, ṣe kí o ṣe,àṣẹ lé àṣẹ, àṣẹ lé àṣẹ;díẹ̀ níhìnín, díẹ̀ ní ọ̀húnbẹ́ẹ̀ ni wọn yóò lọ tí wọn yóò tún ṣubu ṣẹ́yìn,wọn yóò farapa, wọn yóò bọ́ sínú okùna ó sì gbá wọn mú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 28

Wo Àìsáyà 28:13 ni o tọ