Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 28:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ègbé ni fún òdòdó-ẹ̀yẹ náà, tí í ṣeìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Éfáímù,àti sí òdòdó náà tí ń rọ, tí í ṣeògo ẹwàa rẹ̀,tí ó tò sí orí àfonífojì ẹlẹ́tù lójúàti sí ìlú náà ìgbéraga àwọn tía rẹ̀ sílẹ̀ láti ọ̀dọ̀ wáìnì!

2. Kíyèsíì, Olúwa ní ẹnìkan tí ó le tí ó sì lágbára,gẹ́gẹ́ bí ẹ̀wọ́ yìnyín àti bí àtẹ̀gùn apanirun,gẹ́gẹ́ bí àrọ̀ọ̀dá òjò àti òjò tí ómú ẹ̀kún omi wá,òun yóò fi tipátipá sọ ọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 28