Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 27:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ gbẹ, a kán wọn dànùàwọn obìnrin wá wọ́n, sì fi wọ́n dánánítorí àwọn ènìyàn tí òye kò yéni wọ́n jẹ́;Nítorí náà ni Ẹlẹ́dàá wọn kò ṣe yọ́nú sí wọn.Ẹlẹ́dàá wọn kò sì síjú àánú wò wọ́n.

Ka pipe ipin Àìsáyà 27

Wo Àìsáyà 27:11 ni o tọ