Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 26:4-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa títí láé,nítorí Olúwa, Olúwa ni àpátaayérayé náà.

5. Ó sọ àwọn tí ó ń gbé ní òkè di onírẹ̀lẹ̀ó rẹ ìlú agbéraga náà nílẹ̀;ó sọ ọ́ di ilẹ̀ pẹrẹṣẹó sì sọ ọ́ sílẹ̀ nínú erùpẹ̀.

6. Ẹṣẹ̀ tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ẹṣẹ̀ aninilára n nì,ipaṣẹ̀ àwọn òtòsì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26