Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 26:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsíì, Olúwa ń jáde bọ̀ láti ibùgbé e rẹ̀láti jẹ àwọn ènìyàn ilẹ̀ ayé níìyà fún ẹ̀ṣẹ̀ẹ wọn.Ayé yóò sì sọ àwọn ẹ̀jẹ̀ tí a ta sí oríi rẹ̀,kì yóò sì fi àwọn tí a ti pa pamọ́ mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 26

Wo Àìsáyà 26:21 ni o tọ