Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, ìwọ ni Ọlọ́run un mi;Èmi yóò gbé ọ ga èmi ó sìfi ìyìn fún orúkọọ̀ rẹnítorí nínú òtítọ́ aláìlẹ́gbẹ́o ti ṣe ohun ńlá,àwọn ohun tí o ti gbèròo rẹ̀ lọ́jọ́ pípẹ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:1 ni o tọ