Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan Tírè:Pohùnréré, ìwọ ọkọ̀-ojú omi Táṣíṣì!Nítorí a ti pa Tírè runláìsí ilé tàbí èbúté.Láti ilẹ̀ Ṣáípúrọ́sì niọ̀rọ̀ ti wá sọ́dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 23

Wo Àìsáyà 23:1 ni o tọ