Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpátaàti sínú ihò ilẹ̀kúrò lọ́wọ́ ìpayà Olúwaàti ògo ọlá ńlá rẹ̀,nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:19 ni o tọ