Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 19:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò bùkún wọn yóò wí pé, “Ìbùkún ni fún Éjíbítì ènìyàn mi, Áṣíríà iṣẹ́ ọwọ́ mi, àti Ísírẹ́lì ìní mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:25 ni o tọ