Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Olúwa yóò sọ ara rẹ̀ di mímọ̀ fún àwọn ará Éjíbítì àti ní ọjọ́ náà ni wọn yóò gba Olúwa gbọ́. Wọn yóò sìn ín pẹ̀lú ẹbọ ọrẹ oníhóró, wọn yóò jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Olúwa wọn yóò sì mú un ṣẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:21 ni o tọ