Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo pápá-oko Héṣíbónì ti gbẹ,bákan náà ni àjàrà Ṣíbínà rí.Àwọn aláṣẹ àwọn orílẹ̀ èdèwọ́n tẹ àwọn àyànfẹ́ àjàrà mọ́lẹ̀,èyí tí ó ti fà dé Jáṣérìó sì ti tàn dé agbègbè aṣálẹ̀.Àwọn èhu rẹ̀ fọ́n jádeó sì lọ títí ó fi dé òkun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 16

Wo Àìsáyà 16:8 ni o tọ