Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 16:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìfẹ́ a ó fi ìdí ìjọba kan múlẹ̀,ní òdodo ọkùnrin kan yóò jókòó lóríi rẹ̀—ọ̀kan láti ilé Dáfídì wá.Ẹni nní ti ìdájọ́ ń wá ẹ̀tọ́tí ó sì fi ìyára wá ohun tí í ṣe òdodo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 16

Wo Àìsáyà 16:5 ni o tọ