Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibojì tí ó wà ní ìṣàlẹ̀ ni a ru sókèláti pàdé rẹ ní àpadàbọ̀ rẹ̀ó ru ẹ̀mí àwọn tí ó ti lọ ṣókè láti wá kí ọgbogbo àwọn tí ó jẹ́ olórí ní ayéó mú kí wọn dìde lórí ìtẹ́ẹ wọngbogbo àwọn tí ó jọba lórí àwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 14

Wo Àìsáyà 14:9 ni o tọ