Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn orílẹ̀ èdè yóò gbà wọ́nwọn yóò sì mú wọn wá sí àyèe wọn.Ilé Ísírẹ́lì yóò gba àwọn orílẹ̀ èdègẹ́gẹ́ bí àwọn ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrinní ilẹ̀ Olúwa.Wọn yóò kó àwọn akónilẹ́rú wọn ní ìgbèkùnwọn yóò sì jọba lórí àwọn amúnisìn wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 14

Wo Àìsáyà 14:2 ni o tọ