Àìsáyà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Gbọ́ ohùn kan ní àwọn orí òkè,gẹ́gẹ́ bí i ti ogunlọ́gọ̀ ènìyànGbọ́, ìdàrúdàpọ̀ láàrin àwọn ìjọba,gẹ́gẹ́ bí i ti ìkórajọ àwọn orílẹ̀ èdè! Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti kó ogun rẹ̀ jọàwọn jagunjagun fún ogun.