Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohunkóhun kò ní ṣẹ́kù mọ́ bí kò ṣe láti tẹ̀ ba láàrin àwọn ìgbèkùntàbí kí o ṣubú sáàrin àwọn tí a pa.Pẹ̀lú gbogbo nǹkan wọ̀nyí, ìbínú rẹ̀ kò kúrò,ọwọ́ rẹ̀ sì tún gbé sókè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 10

Wo Àìsáyà 10:4 ni o tọ