Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 10:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò nà wọ́n ní ẹgba.Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe lu Mídíánìní òkè Órébù,yóò sì gbé ọ̀páa rẹ̀ lé orí omigẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ní Éjíbítì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 10

Wo Àìsáyà 10:26 ni o tọ