Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ẹwà igbóo rẹ̀, àti àwọn pápá ọlọ́ràágbogbo rẹ̀ ni yóò run pátapáta,gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó sàìṣàn ti í ṣòfò dànù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 10

Wo Àìsáyà 10:18 ni o tọ