Nítorí náà, ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,yóò rán àrùn ìrẹ̀dànù sóríàwọn akíkanjú jagunjagun,lábẹ́ ògo rẹ̀ ni iná kan yóò ti sọgẹ́gẹ́ bí iná ajónirun.