Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 10:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo

2. láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọnàti láti fa ọwọ́ ìdájọ́ sẹ́yìn kúròníwájú àwọn olùpọ́njú ènìyàn mi,wọ́n sọ àwọn ọ̀pọ̀ di ìjẹ fún wọn.Wọ́n sì ń ja àwọn aláìní lólè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 10