Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọbìnrin Ṣíónì ni a fi sílẹ̀gẹ́gẹ́ bí àtíbàbà nínú ọgbà àjàrà,gẹ́gẹ́ bí àbá nínú oko ẹ̀gúsí,àti bí ìlú tí a dótì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:8 ni o tọ