Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Á à! Orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,àwọn ènìyàn tí ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ń pa lẹ́rù,Ìran àwọn aṣebi,àwọn ọmọ tó ti di aṣèbàjẹ́!Wọn ti kọ Olúwa sílẹ̀wọn ti gan Ẹni-Mímọ́ Ísírẹ́lì,wọn sì ti kẹ̀yìn sí i.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:4 ni o tọ