Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. “Ojú yóò tì yín nítorí igi óákù mímọ́èyí tí ẹ ní inú dídùn sía ó kàn yín lábùkù nítorí àwọn ọgbà yìítí ẹ ti yàn fúnra yín.

30. Ẹ ó sì dàbí igi óákù tí ewé rẹ̀ tí,tàbí bí ọgbà tí kò ní omi.

31. Alágbára ọkùnrin náà yóò sì dàbí lẹ́ùiṣẹ́ rẹ̀ bí ẹ̀ṣẹ́-iná,àwọn méjèèjì ni yóò jóná papọ̀,láì sí ẹni tí yóò lè pa iná yìí.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 1