Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn aláṣẹ yín,akẹgbẹ́ àwọn olè,gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.Wọ́n kì í ṣàtìlẹyìn fún ẹ̀tọ́ aláìní baba,ẹjọ́ opó kì í sìí dé iwájú wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:23 ni o tọ