Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ wá ní ìsinsìnyìí, ẹ jẹ́ kí a jọ ṣàsàrò,”ni Olúwa wí.“Bí ẹ̀ṣẹ̀ yín bá rí bí osùn,wọn ó sì funfun bí i yìnyín,bí wọn bá sì pọ́n bí ẹ̀jẹ̀,wọn ó sì dàbí ẹ̀gbọ̀n-òwú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:18 ni o tọ