Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbà sì wí fún ọba pé, “Gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí tí Olúwa mi ọba ti pa láṣẹ fún ìránṣẹ́ rẹ, bẹ́ẹ̀ náà ni ìránṣẹ́ rẹ ó ṣe.” Ọba sì wí pé, “Ní ti Méfibóṣétì, yóò máa jẹun ní ibi oúnjẹ mi, Gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọba.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 9

Wo 2 Sámúẹ́lì 9:11 ni o tọ