Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì ní òkìkí gidigidi nígbà tí ó padà wá ilé láti ibi pípa àwọn ará Síríà ní àfonífojì iyọ̀, àwọn tí o pa jẹ́ ẹgbaàsán ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 8

Wo 2 Sámúẹ́lì 8:13 ni o tọ