Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ọba àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì lọ sí Jérúsálẹ́mù sọ́dọ̀ àwọn ará Jébúsì, àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà; àwọn tí ó sì ti wí fún Dáfídì pé, “Bí kò ṣe pé ìwọ bá mú àwọn afọ́jú àti àwọn arọ́ kúrò, ìwọ kì yóò wọ ìhín wá” wọ́n sì wí pé, “Dáfídì kì yóò lè wá síhìn ín.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:6 ni o tọ