Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì dé Baal-Perasímù, Dáfídì sì pa wọ́n níbẹ̀, ó sì wí pé, “Olúwa ti ya lu àwọn ọta mi níwájú mi, gẹ́gẹ́ bí omi ti ń ya.” Nítorí náà ni òun ṣe pe orúkọ ibẹ̀ náà ni Baal-Perasímù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:20 ni o tọ