Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n wọ ilé náà lọ, òun sì dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀ nínú iyàrá rẹ̀, wọ́n sì pa á, wọ́n sì bẹ́ ẹ lórí, wọ́n gbé orí sá lọ, wọ́n sì fi gbogbo òru rìn ni pẹ̀tẹ́lẹ̀ náà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 4

Wo 2 Sámúẹ́lì 4:7 ni o tọ