Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 3:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kò sáà dè ọ́ lọ́wọ́,bẹ́ẹ̀ ni a kò kan ẹsẹ̀ rẹ ní àbà.Gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí ń ṣubú níwájú àwọn ìkà ènìyàn, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ ṣubú.”Gbogbo àwọn ènìyàn náà sì tún sọkún lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 3

Wo 2 Sámúẹ́lì 3:34 ni o tọ