Wọ́n sì wá sí ìlú olodi Tírè, àti sí gbogbo ìlú àwọn Hífì, àti ti àwọn ará Kénánì: wọ́n sì jáde lọ síhà gúsù ti Júdà, àní sí Bééríṣébà.